Ojukaye Tv Backup

Ojukaye Tv Backup Ojukaye TV is a Nigerian-based media platform that offers a variety of content, including news, entertainment, and educational programs.

This page is for MTEtv to entertain people Everytime everyday, stay tuned.

05/08/2026

ÀWỌN OLÙGBÉ NÀ KEGBAJARE ILÉ BÚBURÚ TI WỌ́N FIRASI PÉ OJE TI ÀWỌN AJÍNIGBÉ NI OTA
​Ìfoya ńlá be sílẹ̀ ní agbègbè Baba T2 / Oko Ewe-Ijagba / Onigbin ni Ota, Ipinle Ogun lẹ́yìn tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn kó jọ sí àyíká ilé kan lórí ẹ̀sùn pé ó jẹ́ ibi tí wọ́n ti n ṣe àwọn ìgbésẹ̀ ìjínigbé.
​Àwọn pẹ́lú àṣẹ ń bọ̀wọ̀ gba àwọn olùgbé nímọ̀ràn láti wà ní àlàáfíà, láti yẹra fún idájọ́ tó lẹ́yìn òfin (jungle justice), àti láti fún àwọn àjọ àbò ní ààyè láti ṣe ìmújáde ẹ̀sùn náà.

Oya ó, Ṣe ẹyin mo wọn? Ẹ̀jẹ̀ ká daruko won
05/08/2026

Oya ó, Ṣe ẹyin mo wọn? Ẹ̀jẹ̀ ká daruko won

04/08/2026

Ìṣẹ̀lẹ̀ ìjínigbé tuntun L'Ondo

Ere idaraya dara fun agọ ara, ki-in-in iwọ ri ninu aworan yii ?
03/08/2026

Ere idaraya dara fun agọ ara, ki-in-in iwọ ri ninu aworan yii ?

🎓 Ibeere ni kiakia fun ọjọ́ Àìkú... Ṣé ẹnikẹ́ni níbí mọ ohun tí "KOS"  to wa lórí fìlà Sam Larry yìí túmọ̀ sí gan-an❓ Tí...
02/08/2026

🎓 Ibeere ni kiakia fun ọjọ́ Àìkú... Ṣé ẹnikẹ́ni níbí mọ ohun tí "KOS" to wa lórí fìlà Sam Larry yìí túmọ̀ sí gan-an❓
Tí o bá mọ̀ ọ́n, kọ ìtumọ̀ rẹ̀ sí abala àwọn ọ̀rọ̀ àlàyé (comments section).

28/07/2026

Ilé alájà méjì kan wọ ilẹ̀ tó sì wó lulẹ̀ pẹ̀lú àwọn èèyàn tó sẹ̀mọ́ inú rẹ̀ ní Ọ̀nà Baale, Ajuwon, Ajọ Agbègbè Ifo, Ìpínlẹ̀ Ògùn.

Nkan yàn fún àwọn Boko Haram. 🔔 🪖 Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ń ṣe ọdún fún àwọn ̀m! !gbé a@fem!sofo lọ́wọ́, Wọ́n gba ibùdó C...
27/07/2026

Nkan yàn fún àwọn Boko Haram.
🔔 🪖 Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ń ṣe ọdún fún àwọn ̀m! !gbé a@fem!sofo lọ́wọ́, Wọ́n gba ibùdó Camp Zairo padà.
Kundus fún àwọn ọmọ ogún Nijeriya 💪💪 🪖 🇳🇬
Ẹ ka ẹkùnrẹ́rẹ́ ìròyìn yí ni WhatsApp Channel Ojukaye Tv👇👇👇👇👇👇👇 https://whatsapp.com/channel/0029VbCAIBdF1YlZHekzMo2g

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn obìnrin ni mo tì pa tì pẹ̀lú àwọn ọmọ Wọn - KWARA 1Ẹ ka ẹkùnrẹ́rẹ́ ìròyìn yí ni WhatsApp Channel Ojukaye...
27/07/2026

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn obìnrin ni mo tì pa tì pẹ̀lú àwọn ọmọ Wọn - KWARA 1
Ẹ ka ẹkùnrẹ́rẹ́ ìròyìn yí ni WhatsApp Channel Ojukaye Tv 👇👇👇👇👇👇👇👇
https://whatsapp.com/channel/0029VbCAIBdF1YlZHekzMo2g

23/07/2026

Ìròyìn Yajo Yajo: Oko ofurufuru ti Enugu Air ṣubú lẹ́ỳí tí ó fẹ́ balẹ̀ sí pákó kọ̀ ọ̀fuurafú.
Ọkàn mi wà pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ìṣẹ̀lẹ̀ ọkọ̀ òfuurufú Enugu Air ní pápákọ̀ òfuurufú Benin kàn. Mo lérò wí pé kò sí ẹni tó farapa, àti pé gbogbo àwọn èrò àti òṣìṣẹ́ inú ọkọ̀ náà wà láìléwu.
​Ó pọn dandan kí àwọn aláṣẹ fi ọwọ́ pàtàkì àti kúnkún mú ọ̀rọ̀ ààbò ìrìn-àjò òfuurufú àti títẹ̀lé àwọn ìlànà iṣẹ́. Kò gbọdọ̀ sí àyè fún àìbìkítà rárá nígbà tí ọ̀rọ̀ bá ti kan ẹ̀mí ènìyàn.

Ṣé Ẹnìkan Lè Gba Owo Kúrò Nínú Àkàǹtì Rẹ Pẹ̀lú Nọ́mbà Àkàǹtì Rẹ Nìkan? Ìdí Òtítọ́ Nìyí”​Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lo máa ń páiya ...
23/07/2026

Ṣé Ẹnìkan Lè Gba Owo Kúrò Nínú Àkàǹtì Rẹ Pẹ̀lú Nọ́mbà Àkàǹtì Rẹ Nìkan? Ìdí Òtítọ́ Nìyí”
​Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lo máa ń páiya tàbí kárà-kàrà máa ń mú wọn tí ẹnìkan bá tọrọ nọ́mbà àkàǹtì rẹ̀ (Account Number).
​Ohun tó máa ń tètè wá sí wọn lórí ni pé:
​"Ṣé eeyan yìí lè pa àkàǹtì banki mi run ni?"
​Ìdí òtítọ́ nìyí. 👇 Ẹka Ẹkùn rẹ́rẹ́ àlàyé nibi👇👇👇👇
https://whatsapp.com/channel/0029VbCAIBdF1YlZHekzMo2g

Address

Iwo Road
Ibadan
10100

Telephone

+2349136963687

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ojukaye Tv Backup posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ojukaye Tv Backup:

Shortcuts

Share