02/08/2026
Èyí ní àṣírí tí ÀFÍN mún ọwọ 👌 burúkú kúrò lára fún ẹnití o ti gbìyànjú t**i nínú aiyé tí gbogbo ohùn tí òún dá ọwọ rẹ lè njà sí pábo fún.
Ti àmìn búburú bá wà lára èèyàn, kòsí ìrù ìgbìyànjú ti ẹni náà lè ṣe, kòní ṣiṣẹ, kódà, wàhálà, ìdààmú ati ìkórira a máa pọ fún irú ẹni bẹẹ. Èmi ÀDÌTÚ BÙKÁTÁ ELÉDÙMARÈ mọ gbà ní Adúrà fún orí kọkan wà wípé wàhálà èmi àti ẹyin ololufẹ mi koni jási asán lasẹ Èdùmàrè! Àmín Àṣẹ 🙏🙏🙏
ÀṢÍRÍ TI A FI Ń MÚN ỌWỌ BÚBURÚ KÚRÒ LÁRA
Egbò túdè òòjọ
Ewé bomubómú 3
Aó gun mọ ọsẹ ìwẹ ẹẹkan péré,.
Aó gbẹ kòtò sí inú igbó tàbí sí ẹyìnkùlé ilé wa, tàbí ibikibi ni abẹ ọrun, aó fi ọsẹ yìí wẹ sínú rẹ, aó ju kàǹnkàn ti a fi wẹ sínú kòtò yìí, aó fi èrùpẹ bòó mọlẹ. Ó tán!.
Yíò b'awa lára mún lasẹ Èdùmàrè! Àmín Àṣẹ! 🙏🙏🙏.