21/08/2026
Thank you Lord.
thanks to Jesus Christ.
oluwa modupe fun Anu re Lori aye mi.
oluwa modupe fun ore ofe re Lori aye
oluwa modupe fun oju rere Lori aye mi.
ope mi Po Lodo re(OLUWA awon oluwa)
Tori aiye kori ibi pamilekun (aiye ko pamilekun)
mo Jo mo yo ni le re
ope ye baba o eh.
aiye ko ni pa emi ati ire lekun loruko Jesu.
SI gbogbo Christiany Lorile ede Nigeria ati ni agbaye.
a ke pe olorun
pe Oluwa gbogbo igbiyanju awon OTA Lori aye mi, pe ki oluwa ki o je ki o ma jasi ofo loruko Jesu.
tun so fun olorun pe
oluwa je ki awon ota ise rere mi ma mu amubo loruko Jesu.
sori ti awon OTA e, ba tile mu amubo Lori Oro aye e, olorun ti wa ise fun awon ota ise rere e ni ye.
o ma pe,
ki awon ota ise rere e ma pan Omi sinu ajadi apere lodaju....iye ni emi ati ire yo fi ma se rere lo SIwaju si.
idi ti o gbodo gba adura ye dada ni
ranti pe opo ati igba ni emi ati ire sun ninu ara sugbon ti olorun un ja fun emi ati ire ninu emi mimo.
boya lo mo pe, nigba ti Iwo sun ninu ara, awon OTA e ko sun ninu ara ati ninu emi okunkun..
nti o fi gbodo so fun olorun ni ohun rara pe, gbogbo igbiyanju awon OTA Lori aye mi, ki o ma jasi ofo, ki o SI ma jasi amubo fun awon ota mi.
SI abala adura elekeji
wa fi nti ojo oni nje gbadura(ojo eti ni oni)
wa so fun olorun
pe Oluwa gbogbo nto je eti ninu aye mi
oluwa fi opin SI.
oni pastor dare tun de, pelu awon awada adura won nun o jare🤓, pe kini adura eti tun ni se ninu gbogbo nto wa ni Ile bayi
eti je nti wa fi opin SI ninu aye e
Ti opin SI gbodo de ba.
o mo nti eti cause sinu aye eniyan ni.
ti o ba di ola ma se, ti o ba di ola ma tun se, ola, ola, ko wa ni tan mo, ti nkan ye ko fi ni se se mo, itumo eti ni ye.
se Iwo olugbo oluka ati oluse ninu oluwa ti wa ri bayi pe, ki se adura awada.
brethren in the Lord
so fun olorun pe
oluwa gbogbo Ogun amubo ninu aye mi
oluwa ba mi sewole patapata loruko Jesu.
tun wa so fun olorun lekan SI
pe Oluwa gbogbo nto le ma cause nto je eti ninu aye mi, oluwa bami da Ina sun gbogbo e ninu aye mi...ri pe o gba adura ye dada.
olorun yo da Ina sun gbogbo nti je amubo ati eti ninu aye temi tire loruko Jesu,Amin.
Awon OTA eniyan ki sinmi ninu emi okunkun
Idi ni ye ti Iwo naa ko fi gbodo sinmi ninu emi mimo nipa adura gbigba.
Anu olorun yo wa wa ri, Anu olorun ko de tun ni fi wa sile ni oruko Jesu, Amin.
Happy weekend everyone
Good morning.
From>>>>>>>>>media damlak concept.