Olorunesan advert media

Olorunesan advert media Just to promote our local business up to standard level

26/10/2019
Haleluya ! !! !!!.Eto karo jesu ti bere ni yen o,Akole ti odun yi ni a pe ni;EGUNGUN GBIGBE,ezekiel 37vs1-14.Eyi ti o ma...
08/02/2019

Haleluya ! !! !!!.Eto karo jesu ti bere ni yen o,Akole ti odun yi ni a pe ni;EGUNGUN GBIGBE,ezekiel 37vs1-14.Eyi ti o ma bere ni ago marun abo owuro t**i di ago meje owuro.Wa jesu pade ninu eto adura owuro yin ki ohun gbogbo ti o di oku ninu aye re ki o le di aye.ninu ijo aposteli ti kristi oke irapada itun nla lo se onigbowo e.olorun babalola be laye.

This work is from Olorunesan investment
27/01/2019

This work is from Olorunesan investment

10/01/2019

PDP. POWER
Kasa ! !! !!!
Say Lado, oke mosan ya o. Ajanakun koja mo ri unkan,bi a ba rerin,ka so pe a rerin.omi titun ti run eja titun ti wo,A soro nipa Hon Oladipupo Adebutu eni nla lo se unkan nla o.Lado for Governor 2019.Messiah omo ipinle Ogun de o.Ti omode ti agba ati okunrin,obinrin,onile ati alejo.E je katun yaya katun yaya lati dibo fun Hon Oladipupo Adebutu fun gomina wa odun2019.Olufe awon mekunu de o lati gboro wa ro,ani ni oruko Ladi ki gbogbo omo ipinle Ogun ki o ma dibo.
2019 Oke mosan straight. Olorunesan advert media.

06/01/2019

My birthday is still ringing

05/01/2019

May God shower his choicest blessings on you. wishing you happiness, good health and a great year ahead. Ademolu adebayo,happy in advance.

08/12/2018

Making a hundred friends is not a miracle.The miracle is to make a single friend who will stand by your side even when hundreds are against you.

09/07/2018

odigbere odiarinako,o tun di oju ala,chief ademolu samuel abatan omo eleda lo da gbere fun aye pe odi gbose,ma okun ma je ekolo oun ti won ba un je laju ile orun ni ko ma ba won je,iku ti pa abiri abiri ti ku,iku ti pa abiri,abiri rorun alakeji ,iku ti pa lenkelenke ni bi to ti fi iye re ke fun,iku na lo pa oba ogboni imole general ,aye e ba mi se idaro eni rere to lo,nigbati mogbo nipa iku baba mi omi ninu popo kan ,mo pa riwo eja nla lo ninu ibu ,ibu pa lolo,aro gidigba lo lale odo,odo palolo ni,erin lo ninu igbo ,igbo pa lolo.ko sa labaro mo,ore ko si mo ,baba lo aye un o tun ri mo o,un o se bi baba ,ko le se bi baba,ta ni o tun gba mi,ko si alabaro mo.

08/06/2018

Olorunesan Investment ile ise kan gbogi ti Olorun oba mi oke tun gbe kale re o,lati se amoju to ayeye lorisirisi b:i Event Planner And Decoration,wedding Cakes, M C for parties, Advertisement, Catering Service, Corps Bearer And Band Set, Ambulance, D.J Service And Musician, House Painting And Electrical Works Abbl. E le kan si wa ni Olorunesan Investment lati ba yi mo ju to eyikeyi ayeye ti e ba fe se, e kan si wa ni addressi yi no:23 odumesi street ipoji sagamu tabi no:23 mojibade mabadeje street off ayepe road sagamu (ile adodi) e pe wa sori number yi 08169463511,e tu le kan si wa lori facebook:user name,ademolu adebayo israel oluwaseun. A wa ni a mu ode dun gbemu,olorun oba lo fun wa se o.! !! !!!.

06/05/2018

We welcome you as we celebrate ,children aniversary ! !! !!!:D:D:D.at oke irapada itun nla ado,which is coming up on the 13th of may 2018.will welcome you all.stay bless in jesus name.announacer : olorunesan advert media.

28/03/2018

We are here to promote your local business at low rate.believe me advert promote business

Address

Shagamu

Telephone

08169463511

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Olorunesan advert media posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share